2 Ọkunrin kan wà, ará Sora, láti inú ẹ̀yà Dani, orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Manoa; àgàn ni iyawo rẹ̀, kò bímọ.
Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 13
Wo Àwọn Adájọ́ 13:2 ni o tọ