Àwọn Adájọ́ 15:17 BM

17 Lẹ́yìn tí ó wí báyìí tán, ó ju egungun ẹ̀rẹ̀kẹ́ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ náà sílẹ̀, wọ́n sì sọ ibẹ̀ ní Ramati Lehi.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 15

Wo Àwọn Adájọ́ 15:17 ni o tọ