Àwọn Adájọ́ 15:4 BM

4 Samsoni bá lọ, ó mú ọọdunrun (300) kọ̀lọ̀kọ̀lọ̀ láàyè, ó wá ìtùfù, ó sì so àwọn kọ̀lọ̀kọ̀lọ̀ náà ní ìrù pọ̀ ní meji meji, ó fi ìtùfù sí ààrin ìrù wọn.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 15

Wo Àwọn Adájọ́ 15:4 ni o tọ