Àwọn Adájọ́ 15:7 BM

7 Samsoni bá sọ fún wọn pé, “Bí ó bá jẹ́ pé bí ẹ óo ti ṣe nìyí n óo gbẹ̀san lára yín, lẹ́yìn náà, n óo fi yín sílẹ̀.”

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 15

Wo Àwọn Adájọ́ 15:7 ni o tọ