Àwọn Adájọ́ 16:16 BM

16 Nígbà tí Delila bẹ̀rẹ̀ sí yọ ọ́ lẹ́nu lemọ́lemọ́, tí ó sì ń rọ̀ ọ́ lojoojumọ, ọ̀rọ̀ náà sú Samsoni patapata.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 16

Wo Àwọn Adájọ́ 16:16 ni o tọ