23 Ní ọjọ́ kan, àwọn ọba Filistini kó ara wọn jọ láti rú ẹbọ ńlá kan sí Dagoni, oriṣa wọn, ati láti ṣe àríyá pé oriṣa wọn ni ó fi Samsoni ọ̀tá wọn lé wọn lọ́wọ́.
Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 16
Wo Àwọn Adájọ́ 16:23 ni o tọ