Àwọn Adájọ́ 16:25 BM

25 Nígbà tí inú wọn dùn, wọ́n ní, “Ẹ pe Samsoni náà wá, kí ó wá dá wa lára yá.” Wọ́n pe Samsoni jáde láti inú ilé ẹ̀wọ̀n, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí dá wọn lára yá. Wọ́n mú un lọ sí ààrin òpó mejeeji pé kí ó dúró níbẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 16

Wo Àwọn Adájọ́ 16:25 ni o tọ