Àwọn Adájọ́ 16:31 BM

31 Àwọn arakunrin rẹ̀, ati gbogbo àwọn ará ilé rẹ̀ bá wá gbé òkú rẹ̀, wọ́n lọ sin ín sáàrin Sora ati Eṣitaolu ninu ibojì Manoa, baba rẹ̀. Ogún ọdún ni ó fi ṣe aṣiwaju ní Israẹli.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 16

Wo Àwọn Adájọ́ 16:31 ni o tọ