6 Delila bá pe Samsoni, ó ní, “Jọ̀wọ́, sọ àṣírí agbára rẹ fún mi, ati bí eniyan ṣe lè so ọ́ lókùn kí eniyan sì kápá rẹ.”
Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 16
Wo Àwọn Adájọ́ 16:6 ni o tọ