Àwọn Adájọ́ 17:10 BM

10 Mika bá sọ fún un pè, “Máa gbé ọ̀dọ̀ mi, kí o sì jẹ́ baba ati alufaa fún mi, n óo máa san owó fadaka mẹ́wàá fún ọ lọ́dún. N óo máa dáṣọ fún ọ, n óo sì máa bọ́ ọ.”

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 17

Wo Àwọn Adájọ́ 17:10 ni o tọ