Àwọn Adájọ́ 18:10 BM

10 Nígbà tí ẹ bá lọ, ẹ óo dé ibìkan tí àwọn eniyan ń gbé láìbẹ̀rù, ilẹ̀ náà tẹ́jú. Dájúdájú Ọlọrun ti fi lé yín lọ́wọ́, kò sí ohun tí eniyan ń fẹ́ ní ayé yìí tí kò sí níbẹ̀.”

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 18

Wo Àwọn Adájọ́ 18:10 ni o tọ