Àwọn Adájọ́ 18:23 BM

23 Wọ́n kígbe pè wọ́n, àwọn ará Dani bá yipada, wọn bi Mika pé, “Kí ní ń dà ọ́ láàmú tí o fi ń bọ̀ pẹlu ọpọlọpọ eniyan báyìí?”

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 18

Wo Àwọn Adájọ́ 18:23 ni o tọ