Àwọn Adájọ́ 18:26 BM

26 Àwọn ará Dani bá ń bá tiwọn lọ, nígbà tí Mika rí i pé wọ́n lágbára ju òun lọ, ó pada sílé rẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 18

Wo Àwọn Adájọ́ 18:26 ni o tọ