Àwọn Adájọ́ 19:16 BM

16 Nígbà tí ó yá, ọkunrin arúgbó kan ń ti oko bọ̀ ní alẹ́; ará agbègbè olókè Efuraimu ni, ṣugbọn Gibea ni ó ń gbé. Àwọn ẹ̀yà Bẹnjamini ni wọ́n ń gbé ìlú náà.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 19

Wo Àwọn Adájọ́ 19:16 ni o tọ