20 Baba arúgbó náà bá dáhùn pé, “Ṣé alaafia ni ẹ dé? Ẹ kálọ, n óo pèsè ohun gbogbo tí ẹ nílò fun yín, ẹ ṣá má sun ìta gbangba níhìn-ín.”
Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 19
Wo Àwọn Adájọ́ 19:20 ni o tọ