Àwọn Adájọ́ 19:8 BM

8 Nígbà tí ó di ọjọ́ karun-un, ọkunrin náà gbéra ní òwúrọ̀ kutukutu láti máa lọ, baba ọmọbinrin náà tún rọ̀ ọ́ pé kí ó fọkàn balẹ̀, kí ó di ìrọ̀lẹ́ kí ó tó máa lọ. Àwọn mejeeji bá jọ jẹun.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 19

Wo Àwọn Adájọ́ 19:8 ni o tọ