Àwọn Adájọ́ 2:12 BM

12 Wọ́n kọ OLUWA Ọlọrun àwọn baba wọn tí ó kó wọn jáde láti ilẹ̀ Ijipti sílẹ̀, wọ́n ń bọ lára àwọn oriṣa àwọn tí wọ́n yí wọn ká, wọ́n ń foríbalẹ̀ fún wọn, wọ́n sì mú inú bí OLUWA.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 2

Wo Àwọn Adájọ́ 2:12 ni o tọ