4 Nígbà tí Angẹli OLUWA sọ ọ̀rọ̀ yìí fún gbogbo àwọn ọmọ Israẹli, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí sọkún tẹ̀dùntẹ̀dùn.
Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 2
Wo Àwọn Adájọ́ 2:4 ni o tọ