Àwọn Adájọ́ 20:15 BM

15 Àwọn ọmọ ogun tí àwọn ará Bẹnjamini kó jọ ní ọjọ́ náà jẹ́ ọ̀kẹ́ kan ati ẹgbaata (26,000) àwọn ọkunrin tí wọn ń lo idà; láì ka àwọn tí wọn ń gbé Gibea tí àwọn náà kó ẹẹdẹgbẹrin (700) akọni ọkunrin jọ.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 20

Wo Àwọn Adájọ́ 20:15 ni o tọ