Àwọn Adájọ́ 20:32 BM

32 Àwọn ará Bẹnjamini wí fún ara wọn pé, “A tún ti tú wọn ká bíi ti iṣaaju.”Ṣugbọn àwọn ọmọ Israẹli wí pé, “Ẹ jẹ́ kí á sá, kí á sì tàn wọ́n kúrò ninu ìlú wọn, kí wọ́n bọ́ sí ojú òpópó.”

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 20

Wo Àwọn Adájọ́ 20:32 ni o tọ