Àwọn Adájọ́ 20:6 BM

6 Mo bá gbé òkú rẹ̀, mo gé e lékìrí lékìrí, mo bá fi ranṣẹ sí gbogbo ilẹ̀ Israẹli jákèjádò, nítorí pé àwọn eniyan wọnyi ti ṣe nǹkan burúkú ati ohun ìríra ní Israẹli.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 20

Wo Àwọn Adájọ́ 20:6 ni o tọ