1 Àwọn ọmọ Israẹli ti búra nígbà tí wọ́n wà ní Misipa pé, “Ẹnikẹ́ni ninu wa kò ní fi ọmọ rẹ̀ fún ará Bẹnjamini.”
Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 21
Wo Àwọn Adájọ́ 21:1 ni o tọ