Àwọn Adájọ́ 21:10 BM

10 Ìjọ eniyan náà bá rán ẹgbaafa (12,000) ninu àwọn jagunjagun wọn tí wọ́n gbójú jùlọ, wọ́n sì fún wọn láṣẹ pé, “Ẹ lọ fi idà pa gbogbo àwọn tí ń gbé Jabeṣi Gileadi ati obinrin wọn, ati àwọn ọmọ wẹ́wẹ́ wọn.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 21

Wo Àwọn Adájọ́ 21:10 ni o tọ