Àwọn Adájọ́ 21:16 BM

16 Àwọn àgbààgbà ìjọ eniyan náà bá bèèrè pé, “Níbo ni a óo ti rí aya fún àwọn tí wọ́n ṣẹ́kù, níwọ̀n ìgbà tí a ti pa àwọn obinrin ẹ̀yà Bẹnjamini run.”

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 21

Wo Àwọn Adájọ́ 21:16 ni o tọ