Àwọn Adájọ́ 21:4 BM

4 Nígbà tí ó di ọjọ́ keji, àwọn eniyan náà dìde ní òwúrọ̀ kutukutu, wọ́n tẹ́ pẹpẹ kan, wọ́n sì rú ẹbọ sísun ati ẹbọ alaafia níbẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 21

Wo Àwọn Adájọ́ 21:4 ni o tọ