Àwọn Adájọ́ 3:12 BM

12 Àwọn ọmọ Israẹli tún ṣe ohun tí ó burú lójú OLUWA, OLUWA sì fún Egiloni, ọba ilẹ̀ Moabu, lágbára lórí wọn, nítorí pé wọ́n ṣe ohun tí ó burú lójú OLUWA.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 3

Wo Àwọn Adájọ́ 3:12 ni o tọ