Àwọn Adájọ́ 3:17 BM

17 Ó fi ìṣákọ́lẹ̀ náà jíṣẹ́ fún Egiloni, ọba ilẹ̀ Moabu. Egiloni yìí jẹ́ ẹni tí ó sanra rọ̀pọ̀tọ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 3

Wo Àwọn Adájọ́ 3:17 ni o tọ