Àwọn Adájọ́ 3:29 BM

29 Wọ́n pa àwọn alágbára ati akikanju bí ẹgbaarun (10,000) ninu àwọn ará Moabu, kò sì sí ẹnìkan tí ó là ninu wọn.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 3

Wo Àwọn Adájọ́ 3:29 ni o tọ