Àwọn Adájọ́ 3:31 BM

31 Aṣiwaju tí ó tún dìde lẹ́yìn Ehudu ni Ṣamgari, ọmọ Anati, ẹni tí ó fi ọ̀pá tí wọ́n fi ń da mààlúù pa ẹgbẹta (600) ninu àwọn ará Filistia; òun náà gba Israẹli kalẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 3

Wo Àwọn Adájọ́ 3:31 ni o tọ