Àwọn Adájọ́ 3:4 BM

4 Àwọn ni OLUWA fi dán àwọn ọmọ Israẹli wò, láti wò ó bóyá wọn óo mú àṣẹ tí òun pa fún àwọn baba wọn láti ọwọ́ Mose ṣẹ, tabi wọn kò ní mú un ṣẹ.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 3

Wo Àwọn Adájọ́ 3:4 ni o tọ