Àwọn Adájọ́ 4:10 BM

10 Baraki bá pe àwọn ọmọ Sebuluni ati Nafutali sí Kedeṣi; ẹgbaarun (10,000) ọkunrin ninu wọn ni wọ́n tẹ̀lé Baraki, Debora náà sì bá wọn lọ.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 4

Wo Àwọn Adájọ́ 4:10 ni o tọ