Àwọn Adájọ́ 4:5 BM

5 Lábẹ́ ọ̀pẹ kan, tí wọ́n sọ ní ọ̀pẹ Debora, tí ó wà láàrin Rama ati Bẹtẹli ní agbègbè olókè ti Efuraimu ní í máa ń jókòó sí, ibẹ̀ ni àwọn ọmọ Israẹli tií máa ń lọ bá a fún ìdájọ́.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 4

Wo Àwọn Adájọ́ 4:5 ni o tọ