Àwọn Adájọ́ 5:11 BM

11 Ẹ tẹ́tí sí ohùn àwọn akọrin lẹ́bàá odò,ibẹ̀ ni wọ́n ti ń sọ̀rọ̀ nípa ìṣẹ́gun OLUWA,ọ̀rọ̀ ìṣẹ́gun àwọn eniyan rẹ̀ ní Israẹli.Àwọn eniyan OLUWA sì yan jáde láti ẹnubodè ìlú wọn.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 5

Wo Àwọn Adájọ́ 5:11 ni o tọ