Àwọn Adájọ́ 5:16 BM

16 Kí ló dé tí o fi dúró lẹ́yìn láàrin àwọn agbo aguntan?Tí o fi ń gbọ́ bí àwọn olùṣọ́-aguntan ti ń fọn fèrè fún àwọn aguntan wọn.Àwọn ẹ̀yà Reubẹni ṣiyèméjì,ìmọ̀ wọn kò ṣọ̀kan láti wá.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 5

Wo Àwọn Adájọ́ 5:16 ni o tọ