24 Ẹni ibukun jùlọ ni Jaeli láàrin àwọn obinrin,Jaeli, aya Heberi, ọmọ Keni,ẹni ibukun jùlọ láàrin àwọn obinrin tí ń gbé inú àgọ́.
Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 5
Wo Àwọn Adájọ́ 5:24 ni o tọ