Àwọn Adájọ́ 5:30 BM

30 “Ṣebí ìkógun ni wọ́n ń wá, tí wọ́n sì ń pín?Obinrin kan tabi meji fún ọkunrin kọ̀ọ̀kan,ìkógun àwọn aṣọ aláró fún Sisera,ìkógun àwọn aṣọ aláró tí wọ́n dárà sí lára,aṣọ ìborùn aláró meji tí wọ́n dárà sí lára fún èmi náà?”

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 5

Wo Àwọn Adájọ́ 5:30 ni o tọ