4 OLUWA, nígbà tí o jáde lọ láti òkè Seiri,nígbà tí o jáde lọ láti agbègbè Edomu,ilẹ̀ mì tìtì,omi bẹ̀rẹ̀ sí bọ́,ọ̀wààrà òjò bẹ̀rẹ̀ sí rọ̀.
Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 5
Wo Àwọn Adájọ́ 5:4 ni o tọ