Àwọn Adájọ́ 6:18 BM

18 Jọ̀wọ́, má kúrò níhìn-ín títí tí n óo fi mú ẹ̀bùn mi dé, tí n óo sì gbé e kalẹ̀ níwájú rẹ.”Angẹli náà dá Gideoni lóhùn, ó ní, “N óo dúró títí tí o óo fi pada dé.”

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 6

Wo Àwọn Adájọ́ 6:18 ni o tọ