Àwọn Adájọ́ 6:20 BM

20 Angẹli Ọlọrun náà wí fún un pé, “Da ẹran náà ati burẹdi tí kò ní ìwúkàrà ninu náà sí orí àpáta yìí, kí o sì da omi ọbẹ̀ náà lé gbogbo rẹ̀ lórí.” Gideoni sì ṣe bẹ́ẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 6

Wo Àwọn Adájọ́ 6:20 ni o tọ