Àwọn Adájọ́ 6:35 BM

35 Ó ranṣẹ jákèjádò ilẹ̀ Manase, wọ́n pe ara wọn jáde, wọ́n sì tẹ̀lé e. Ó tún ranṣẹ bákan náà sí ẹ̀yà Aṣeri, ẹ̀yà Sebuluni, ati ẹ̀yà Nafutali, àwọn náà sì lọ pàdé rẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 6

Wo Àwọn Adájọ́ 6:35 ni o tọ