Àwọn Adájọ́ 6:40 BM

40 Ọlọrun tún ṣe bẹ́ẹ̀ ní alẹ́ ọjọ́ náà, nítorí pé, orí irun yìí nìkan ṣoṣo ni ó gbẹ, ìrì sì sẹ̀ sí gbogbo ilẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 6

Wo Àwọn Adájọ́ 6:40 ni o tọ