Àwọn Adájọ́ 7:11 BM

11 O óo gbọ́ ohun tí wọ́n ń sọ, lẹ́yìn náà, o óo ní agbára láti lè gbógun ti àgọ́ náà.” Gideoni bà mú Pura, iranṣẹ rẹ̀, wọ́n jọ lọ sí ìpẹ̀kun ibi tí àwọn tí wọ́n di ihamọra ogun ninu àgọ́ wọn wà.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 7

Wo Àwọn Adájọ́ 7:11 ni o tọ