Àwọn Adájọ́ 7:14 BM

14 Ẹnìkejì rẹ̀ dá a lóhùn, ó ní, “Èyí kì í ṣe ohun mìíràn, bíkòṣe idà Gideoni, ọmọ Joaṣi, ọ̀kan ninu àwọn ọmọ Israẹli. Ọlọrun ti fi Midiani ati gbogbo ọmọ ogun rẹ̀ lé e lọ́wọ́.”

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 7

Wo Àwọn Adájọ́ 7:14 ni o tọ