Àwọn Adájọ́ 7:23 BM

23 Àwọn ọmọ ogun Israẹli pe àwọn ọkunrin Israẹli jáde láti inú ẹ̀yà Nafutali, ati ti Aṣeri ati ti Manase, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí lé àwọn ará Midiani lọ.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 7

Wo Àwọn Adájọ́ 7:23 ni o tọ