Àwọn Adájọ́ 7:3 BM

3 Nítorí náà, kéde fún gbogbo wọn pé, kí ẹnikẹ́ni tí ẹ̀rù bá ń bà pada sí ilé.” Gideoni bá dán wọn wò lóòótọ́, ọ̀kẹ́ kan ati ẹgbaa (22,000) ọkunrin ninu wọn sì pada sí ilé. Àwọn tí wọ́n kù jẹ́ ẹgbaarun (10,000).

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 7

Wo Àwọn Adájọ́ 7:3 ni o tọ