Àwọn Adájọ́ 7:7 BM

7 OLUWA bá wí fún Gideoni pé, “Àwọn ọọdunrun (300) tí wọ́n fi ahọ́n lá omi ni n óo lò láti gbà yín là, n óo sì fi àwọn ará Midiani lé ọ lọ́wọ́. Jẹ́ kí àwọn yòókù pada sí ilé wọn.”

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 7

Wo Àwọn Adájọ́ 7:7 ni o tọ