Àwọn Adájọ́ 8:1 BM

1 Àwọn ará Efuraimu bèèrè lọ́wọ́ Gideoni pé, “Irú kí ni o ṣe yìí, tí o kò pè wá, nígbà tí o lọ gbógun ti àwọn ara Midiani?” Wọ́n bá bẹ̀rẹ̀ sí sọ̀rọ̀ sí i pẹlu ibinu.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 8

Wo Àwọn Adájọ́ 8:1 ni o tọ