Àwọn Adájọ́ 8:14 BM

14 Ọwọ́ rẹ̀ tẹ ọdọmọkunrin ará Sukotu kan, ó sì bèèrè orúkọ àwọn olórí ati àwọn àgbààgbà ìlú Sukotu lọ́wọ́ rẹ̀. Ọdọmọkunrin yìí sì kọ orúkọ wọn sílẹ̀, wọ́n jẹ́ ọkunrin mẹtadinlọgọrin.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 8

Wo Àwọn Adájọ́ 8:14 ni o tọ