Àwọn Adájọ́ 8:27 BM

27 Gideoni bá fi wúrà yìí ṣe ère Efodu kan, ó gbé e sí ìlú rẹ̀ ní Ofira, gbogbo àwọn ọmọ Israẹli sì bẹ̀rẹ̀ sí bọ ère oriṣa yìí, ó sì di tàkúté fún Gideoni ati ìdílé rẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 8

Wo Àwọn Adájọ́ 8:27 ni o tọ