Àwọn Adájọ́ 8:35 BM

35 Wọn kò ṣe ìdílé Gideoni dáradára bí ó ti tọ́, gẹ́gẹ́ bí ẹ̀san gbogbo nǹkan dáradára tí òun náà ti ṣe fún Israẹli.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 8

Wo Àwọn Adájọ́ 8:35 ni o tọ